Ara, e ba mi ka lo,
Pade Oluwa mi o,
Ara, e ba mi ka lo,
Pade Oluwa mi o,
Ni Bethlehemu,
Ni Ilu ayo,
Ni Bethlehemu,
Ni I lu ayo.
2. Awon Angeli njo,
Awon Maleka nyo,
Awon Angeli njo,
Awon Maleka nyo,
Nwon nke Hossanah,
S’Omo Dafidi,
Nwon nke Hossanah,
S’Omo Dafidi. Amin
No comments:
Post a Comment